Jóòbù 15:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun kì yóò jáde kúrò nínúòkùnkùn; ọ̀wọ́ iná ni yóò jóẹ̀ka rẹ̀, àti nípaṣẹ̀ ẹ̀mí ẹnu rẹ̀ní yóò máa kọjá lọ kúrò.

Jóòbù 15

Jóòbù 15:21-34