Jóòbù 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ìwọ fi yí ẹ̀mí rẹ padà lòdì síỌlọ́run, tí ó fi ń jẹ́ ki ọ̀rọ̀kọ́rọ̀kí ó máa bọ́ ní ẹnu rẹ̀ bẹ́ẹ̀?

Jóòbù 15

Jóòbù 15:7-21