Jóòbù 15:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ígbà náà ní Élífásì, ará Témà, dáhùn wí pé:

2. “Ọlọ́gbọ́n a máa sọ̀rọ̀ ìmọ̀ asán, kíó sì máa fi afẹ́fẹ́ ìlà oòrun kún ara rẹ̀ nínú?

3. Òun lè máa fi àròyé sọ̀rọ̀ tí kò níèrè, tàbí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ nínú èyí tí kò lè fi ṣe rere?

Jóòbù 15