Jóòbù 14:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ rẹ̀ bọ́ sí ipò ọlá, òunkò sì mọ̀; wọ́n sì rẹ̀ sílẹ̀,òun kò sì kíyèsìí lára wọn.

Jóòbù 14

Jóòbù 14:12-22