Jóòbù 14:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Omi a máa yinrin òkúta, ìwọ a sìmú omi ṣàn bo ohun tí ó hù jáde lóri ilẹ̀,ìwọ sì sọ ìrètí ènìyàn dí òfo.

Jóòbù 14

Jóòbù 14:10-22