Jóòbù 14:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Áà! ìwọ ìbá fi mí pamọ́ ní ipò òkú,kí ìwọ kí ó fi mí pamọ́ ní ìkọ̀kọ̀,títí ìbínú rẹ yóò fi rékọjá,ìwọ ìbá lànà ìgbà kan sílẹ̀ fún mi, kí ó si rántí mi!

Jóòbù 14

Jóòbù 14:3-19