Jóòbù 14:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ènìyàn tí a bí nínú obìnrinọlọ́jọ́ díẹ̀ ni, ó sì kún fún ìpọ́njú.

2. Ó jáde wá bí ìtànná ewéko, a sìké e lulẹ̀; Ó sì ń fò lọ bí òjìji, kò sì dúró pẹ́.

Jóòbù 14