Jóòbù 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àgọ́ àwọn ìgárá ń bẹ̀rù;àwọn tí ó sì ń mú Ọlọ́run bínú wà láìléwu,àwọn ẹni tí ó sì gbá òrìṣà mú ní ọwọ́ wọn.

Jóòbù 12

Jóòbù 12:1-7