Jóòbù 12:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn a máa fi ọwọ́ ta ilẹ̀ nínú òkùnkùn níbi tí kò sí ìmọ́lẹ̀,Òun a sì máa mú wọn tàsé ìrìn bí ọ̀mùtí.

Jóòbù 12

Jóòbù 12:17-25