Jóòbù 11:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ga ju àwọn ọ̀run lọ; kí ni ìwọ le è ṣe?Ó jìn ju jíjìn isà òkú lọ; kí ni ìwọ le mọ̀?

Jóòbù 11

Jóòbù 11:1-17