Jóòbù 11:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé àmọ̀tàn rẹ le mú ènìyàn pa ẹnu wọn mọ́ bí?Ṣé ẹnikẹ́ni kò ní bá ọ wí bí ìwọ bá yọ ṣùtì sí ni?

Jóòbù 11

Jóòbù 11:1-7