Jóòbù 11:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìwọ bá gbé ẹ̀ṣẹ̀ tí ń bẹ ní ọwọ́ rẹ jù sọnù,tí ìwọ kò sì jẹ́ kí aburú gbé nínú àgọ́ rẹ.

Jóòbù 11

Jóòbù 11:6-20