Jóòbù 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi bẹ̀ ọ́ rántí pé ìwọ tí ìwọ timọ mí bí amọ̀; ìwọ yóò ha sìtún mú mi lọ padà sí erùpẹ̀?

Jóòbù 10

Jóòbù 10:8-14