Jóòbù 10:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ha tọ́ tí ìwọ ì bá fi máa ni mílára, tí ìwọ ìbá fi máa gan iṣẹ́ọwọ́ rẹ tí ìwọ yóò fi máa tànìmọ́lẹ̀ sí ìmọ̀ ènìyàn búrurú.

Jóòbù 10

Jóòbù 10:2-11