Jónà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa Ọlọ́run sì pesè ìtàkùn kan, ó ṣe é kí ó gòkè wá sórí Jónà; kí ó lè ṣe ìji bò ó lórí; láti gbà á kúrò nínú ìbànújẹ́ rẹ̀. Jónà sì yọ ayọ̀ ńlá nítorí ìtàkùn náà.

Jónà 4

Jónà 4:2-11