Jónà 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni mo wí pé,‘a ta mí nù kúrò níwájú rẹ;ṣùgbọ́n ṣíbẹ̀ èmi yóò túnmáa wo ìhà tẹ́ḿpìlì mímọ́ rẹ.’

Jónà 2

Jónà 2:1-9