Jónà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Dìde lọ sí ìlú ńlá Nínéfè kí o sì wàásù sí i, nítorí ìwà búburú rẹ̀ gòkè wá iwájú mi.”

Jónà 1

Jónà 1:1-9