Jónà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn ọkùnrin náà bẹ̀rù Olúwa gidigidi, wọn si rúbọ sí Olúwa, wọ́n sì jẹ́ ẹ̀jẹ́.

Jónà 1

Jónà 1:7-17