Jòhánù 9:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì wí pé, “Nítorí ìdájọ́ ni mo ṣe wá sí ayé yìí, kí àwọn tí kò ríran lè ríran; àti kí àwọn tí ó ríran lè di afọ́jú.”

Jòhánù 9

Jòhánù 9:35-41