Jòhánù 9:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa mọ̀ pé Ọlọ́run kì í gbọ́ ti ẹlẹ́ṣẹ̀; ṣùgbọ́n bí ẹnìkan bá ṣe olùfọkànsìn sí Ọlọ́run, tí ó bá sì ń ṣe ìfẹ́ rẹ̀, Òun ni ó ń gbọ́ tirẹ̀.

Jòhánù 9

Jòhánù 9:29-34