Jòhánù 9:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa mọ̀ pé Ọlọ́run bá Mósè sọ̀rọ̀: ṣùgbọ́n bí ó ṣe ti eleyìí, àwa kò mọ ibi tí ó ti wá.”

Jòhánù 9

Jòhánù 9:26-30