Jòhánù 8:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, Bí ẹnìkan bá pa ọ̀rọ̀ mi mọ́, kì yóò rí ikú láéláé.”

Jòhánù 8

Jòhánù 8:41-54