Jòhánù 7:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé kò sí ẹnikẹ́ni tí í ṣe ohunkóhun níkọ̀kọ̀, tí òun tìkáarẹ̀ sì ń fẹ́ kí a mọ òun ní gbangba. Bí ìwọ bá ń ṣe nǹkan wọ̀nyí, fi ara rẹ hàn fún aráyé.”

Jòhánù 7

Jòhánù 7:3-7