Jòhánù 7:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Ṣùgbọ́n ó sọ èyí ní ti ẹ̀mí, tí àwọn tí ó gbà á gbọ́ ń bọ̀ wá gbà: nítorí a kò tí ì fi ẹ̀mí mímọ́ fúnni; nítorí tí a kò tí ì ṣe Jésù lógo.)

Jòhánù 7

Jòhánù 7:38-48