Jòhánù 7:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ń sọ ti ara rẹ̀ ń wá ògo ara rẹ̀: ṣùgbọ́n ẹni tí ń wá ògo ẹni tí ó rán an, òun ni olóòótọ́, kò sì sí àìsòdodo nínú rẹ̀.

Jòhánù 7

Jòhánù 7:14-22