Jòhánù 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dáhùn, ó sì wí pé, “Ẹ̀kọ́ mi kì í ṣe tèmi, bí kò ṣe ti ẹni tí ó rán mi.

Jòhánù 7

Jòhánù 7:10-22