Jòhánù 7:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí Jésù ńrìn ní Gálílì: nítorí tí kò fẹ́ẹ́ rìn ní Jùdéà, nítorí àwọn Júù ń wá a láti pa.

2. Àjọ àwọn Júù tí í ṣe àjọ àgọ́ súnmọ́ etílé tan.

Jòhánù 7