Jòhánù 6:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni oúnjẹ tí ó ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, kí ènìyàn lè máa jẹ nínú rẹ̀ kí ó má sì kú.

Jòhánù 6

Jòhánù 6:40-53