Jòhánù 6:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè wá sọ́dọ̀ mi, bí kò ṣe pé Baba tí ó rán mi fà á: Èmi ó sì jí i dìde níkẹyìn ọjọ́.

Jòhánù 6

Jòhánù 6:40-46