Jòhánù 6:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí sì ni ìfẹ́ ẹni tí ó rán mi, pé ẹnikẹ́ni tí ó bá wo ọmọ, tí ó bá sì gbà á gbọ́, kí ó lè ní ìyè àìnípẹ̀kun: Èmi ó sì jí i dìde níkẹyìn ọjọ́.”

Jòhánù 6

Jòhánù 6:31-47