Jòhánù 6:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo èyí tí Baba fi fún mi, yóò tọ̀ mí wá; ẹni tí ó bá sì tọ̀ mí wá, èmi kì yóò tà á nù, bí ó tí wù kó rí.

Jòhánù 6

Jòhánù 6:31-41