Jòhánù 6:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì gun orí òkè lọ, níbẹ̀ ni ó sì gbé jókòó pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yin rẹ̀.

Jòhánù 6

Jòhánù 6:1-13