Jòhánù 6:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dáhùn, ó sì wí fún wọn pé, “Èyí ni iṣe Ọlọ́run pé, kí ẹ̀yin gba ẹni tí ó rán an gbọ́.”

Jòhánù 6

Jòhánù 6:27-30