Jòhánù 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì wí pé, “Ẹ mú kí àwọn ènìyàn náà jókòó!” Kóríkó púpọ̀ sì wá níbẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọkùnrin náà jókòó; ìwọ̀n ẹgbẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n ènìyàn ní iye.

Jòhánù 6

Jòhánù 6:2-19