Jòhánù 5:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ má ṣe rò pé, èmi ó fi yín sùn lọ́dọ̀ Baba: ẹni tí ń fi yín sùn wà, àní Mósè, ẹni tí ẹ̀yin gbẹ́kẹ̀lẹ́.

Jòhánù 5

Jòhánù 5:36-47