Jòhánù 5:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi wá ní orúkọ Baba mi, ẹ̀yin kò sì gbà mí; bí ẹlòmíràn bá wá ní orúkọ ara rẹ̀, òun ni ẹ̀yin yóò gbà.

Jòhánù 5

Jòhánù 5:41-47