Jòhánù 5:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti Baba tìkárarẹ̀ tí ó rán mi ti jẹ́rí mi. Ẹ̀yin kò gbọ́ ohùn rẹ̀ nígbà kan rí, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò rí ìrísí rẹ̀.

Jòhánù 5

Jòhánù 5:32-43