Jòhánù 5:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni fìtílà tí ó ń jó, tí ó sì ń tànmọ́lẹ̀: ẹ̀yin sì fẹ́ fún sáà kan láti máa yọ̀ nínú ìmọ́lẹ̀ rẹ̀.

Jòhánù 5

Jòhánù 5:29-42