Jòhánù 5:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé gẹ́gẹ́ bí Baba ti ń jí òkú dìde, tí ó sì ń sọ wọ́n di alàyè: bẹ́ẹ̀ ni ọmọ ń sọ àwọn tí ó fẹ́ di alàyè pẹ̀lú.

Jòhánù 5

Jòhánù 5:16-26