Jòhánù 5:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin náà lọ, ó sì sọ fún àwọn Júù pé, Jésù ni ẹni tí ó mú òun láradá.

Jòhánù 5

Jòhánù 5:14-24