Jòhánù 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin ará Samáríà náà sọ fún un pé, “Júù ni ẹ́ obìnrin ará Samáríà ni èmi. Eéti rí tí ìwọ ń bèèrè ohun mímu lọ́wọ́ mi?” (Nítorí tí àwọn Júù kì í bá àwọn ará Samaríà ṣe pọ̀.)

Jòhánù 4

Jòhánù 4:1-15