Jòhánù 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ó dé ìlú Samaríà kan, tí a ń pè ní Síkárì, tí ó súnmọ́ etí ilẹ̀ oko tí Jákọ́bù ti fi fún Jóṣéfù, ọmọ rẹ̀.

Jòhánù 4

Jòhánù 4:1-15