Jòhánù 4:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Nítorí Jésù tìkararẹ̀ ti jẹ́rìí wí pé, Wòlíì kì í ní ọlá ní ilẹ̀ Òun tìkárarẹ̀.)

Jòhánù 4

Jòhánù 4:37-53