Jòhánù 4:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lórí èyí ni àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ dé, ẹnu sì yà wọ́n pé ó ń bá obìnrin sọ̀rọ̀: ṣùgbọ́n kò sí ẹnì kan tí ó wí pé, “Kíni ìwọ ń wá?” tàbí “Èéṣe tí ìwọ fi ń bá a sọ̀rọ̀?”

Jòhánù 4

Jòhánù 4:25-33