Jòhánù 4:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin náà wí fún un pé, mo mọ̀ pé, “Mèsáyà ń bọ̀ wá, tí a ń pè ní Krísítì: Nígbà tí Òun bá dé, yóò sọ ohun gbogbo fún wa.”

Jòhánù 4

Jòhánù 4:24-28