Jòhánù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dáhùn, ó sì wí fún un pé, “Ẹnikẹ́ni tí ó bá mu nínú omi yìí, òrùngbẹ yóò tún gbẹ ẹ́:

Jòhánù 4

Jòhánù 4:12-21