Jòhánù 3:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹni tí ó ti òkè wá ju gbogbo ènìyàn lọ; ẹni tí ó ti ayé wá ti ayé ni, a sì máa sọ ohun ti ayé. Ẹni tí ó ti ọ̀run wá ju gbogbo ènìyàn lọ.

Jòhánù 3

Jòhánù 3:26-36