Jòhánù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí olúkúlùkù ẹni tí ó bá hùwà búburú níí ìkórìíra ìmọ́lẹ̀, kìí sí wá sí ìmọ́lẹ̀, kí a má ṣe bá iṣẹ́ rẹ̀ wí.

Jòhánù 3

Jòhánù 3:13-27