Jòhánù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sì sí ẹni tí ó gòkè re ọ̀run bí kò ṣe ẹni tí ó ti ọ̀run sọ̀kalẹ̀ wá, Ọmọ Ènìyàn tí ń bẹ ní ọ̀run.

Jòhánù 3

Jòhánù 3:8-16