Jòhánù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin kan sì wà nínú àwọn Farisí, tí a ń pè ní Níkódémù, ìjòyè kan láàrin àwọn Júù:

Jòhánù 3

Jòhánù 3:1-6